Sola Allyson ft. Adekunle Gold – Alujanjankijan
Sola Allyson links with Adekunle Gold on “Alujanjangijan”.
Nigerian female singer Sola Allyson dropped a new song titled “Alujanjangijan“, featuring Adekunle Gold.
Listen to the audio below:
Alujanjankijan Lyrics:
Iya, Iya ta’kun wa’le- Alujanjankijan
Iya, Iya ta’kun wa’le- Alujanjankijan
E ma f’omo s’ile fun’ya je- Alujanjankijan
Eni t’o bi’mo lo ye k’o w’omo- Alujanjankijan
(VERSE 1- Sola Allyson)
Ba mi n’omo mi, o ye k’o de’nu olomo
Oju merin lo n bi’mo, sugbon, igba oju li n w’omo
Omo t’a o ko, a gbe’le t’a ko ta
Omo t’a o to, a k’eso t’a ni ta
Omo n’igbeyin, omo l’ola, omo l’ola, omo n’iyi, omo l’ade
Omo l’ewa, omo l’eso oh ohhh
O da a, bi o da a- o le da a; o san, bi o san- a de san
Igboya at’adura ni o gba- yi o da ahhh
(Sola Allyson- CHORUS)
Iya, Iya ta’kun wa’le- Alujanjankijan
Iya, Iya ta’kun wa’le- Alujanjankijan
E ma f’omo s’ile fun’ya je- Alujanjankijan
Eni t’o bi’mo lo ye k’o w’omo e; e t’omo- Alujanjankijan
(VERSE 2- Adekunle Gold)
Ori fun wa l’omo’re bi i ti Samuel oh
Won ko Samu, o gb’eko oh, o si se’hun rere
If you spare the rod, you go spoil the child; I hope you know?
Train them with the love of God; abegi oh
Tori, alaigboran omo- asa ni
Agba o kunwo l’oju- asa ni
Agba o jo won l’oju oh- asa ni
Agba iya ni o da- asa ni
Alalugboran omo oh- omo ni
Won le d’eyan l’ola- omo ni
T’a ba to won daada o- omo ni
Won le d’eyan l’ola
(Adekunle Gold- CHORUS)
Iya, Iya ta’kun wa’le oh- Alujanjankijan
Iya, Iya ta’kun wa’le oh- Alujanjankijan
Eni t’o bi’mo lo ye k’o w’omo oh- Alujanjankijan
E ma f’omo s’ile fun’ya je oh- Alujanjankijan
(CHORUS- Sola Allyson)
Iya, Iya ta’kun wa’le oh ohh- Alujanjankijan
E ma f’omo s’ile fun’ya je ohh- Alujanjankijan
Eni t’o bi’mo e lo ye k’o w’omo e; e t’omo- Alujanjankijan
Iya, baba, t’akun wa’le- Alujanjankijan
Follow Us
Do you find Xclusiveloaded useful? Click here to give us five stars rating!
suliat
5 years ago
great song..undiluted